Vocabulary

Phrases

Grammar

Yoruba Directions

These are expressions used when giving or getting directions in Yoruba. Very useful when trying to find your way around or when lost.

Excuse me! (to ask someone): Ẹ jọ̀wọ́!
Can you show me?: Ṣé ẹ lè fi hàn mi?
I'm lost: Mo ti ṣìnà
I'm not from here: Ìhín kọ́ ni mo ti wá
Can I help you?: Njẹ́ mo lè ràn ọ́ lọ́wọ́?
Can you help me?: Njẹ́ o lè ràn mí lọ́wọ́?
It's near here: Ó súnmọ́ ìhín
It's far from here: Ó jìnnà sí ìhín
Go straight: Lọ tààrà
Turn left: Yà sí òsì
Turn right: Yà sí ọ̀tún
One moment please!: Ẹ jọ̀wọ́ ní ìṣẹ́jú kan!
Come with me!: [Ẹ] tẹ̀lé mi!
How can I get to the museum? : Báwo ni mo ti lè dé ilé nnkan ìṣẹ̀mbáyé?
How long does it take to get there?: Báwo ni yóò ti pẹ́ tó láti dé ibẹ̀?
Downtown (city center): Ààrin gbùngbùn ìlú

The following are words which might be used alone or in combination with other words to ask or give directions.

Near: Súnmọ́
Far: Jìnnà
Right: Ọ̀tún
Left: Òsì
Straight: Tààrà
There: Ọ̀hún
Here: Ìhín
To walk: Láti rìn
To drive: Láti wakọ̀
To turn: Láti yí padà
Traffic light: Iná tí ó ndarí ọkọ̀

We hope you will not need to ask for directions in Yoruba. If you do need help then the above sentences are essential. Check our menu above to select another topic or click the "Next" button to view the next lesson.

Yoruba SurvivalPrevious lesson:

Yoruba Survival

Next lesson:

Yoruba Weather

Yoruba Weather